Arise ni arika, arika si ni baba iregun, ọpọ ohun ti a ba se ni oni, n bọ wa di itan to ba di ọla. Idi ree ti iran Yoruba ko fi lee gbagbe ipa manigbagbe ti Ọba Seriki Ifaremilekun ...